ORISUN lai, t’ ayo gbogbo
ORISUN lai, t’ ayo gbogbo, Ki iyin Re gba enu wa, Nigbat’ a wa sinu ‘le Re, ‘Wo-t’ ore Re buk’ odun wa.
Read hymn : ORISUN lai, t’ ayo gbogboORISUN lai, t’ ayo gbogbo, Ki iyin Re gba enu wa, Nigbat’ a wa sinu ‘le Re, ‘Wo-t’ ore Re buk’ odun wa.
Read hymn : ORISUN lai, t’ ayo gbogboYIN Olorun Oba wa; E gbe ohun iyin ga; Anu Re o wa titi, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waGB’ ope mi, Oluwa, Lat’ okan l’ o ti wa, Iwo t’ O gba die opo, K’yo kegan ‘more mi.
Read hymn : GB’ ope mi, OluwaA F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo;
Read hymn : A F’ ope f’ OlorunAWA nbebe fun ‘le wa, Ki Afrika ko pe; K’ Olorun Olodumare, Fi alafia fun u.
Read hymn : AWA nbebe fun ‘le waOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waAYIN O, Oluranwo wa, T’ife Re wa bakanna lai, Owo ike en’t’ o bere, Ti o si pari odun wa.
Read hymn : AYIN O, Oluranwo waOLUWA fi apa Re han, Si jek’a r’ ogo Re, Ki gbogbo wa ri ami Re, K’ o m’ okan lile ro.
Read hymn : OLUWA fi apa Re hanOJO ati akoko nlo, Nwon nsun wa s’ eti ‘boji; Awa fere dubule na, Ninu iho ‘busun wa.
Read hymn : OJO ati akoko nloBABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa:
Read hymn : BABA, je nya odun yiODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo;
Read hymn : ODUN miran ti koja