OJO ‘mole l’ eyi
OJO ‘mole l’ eyi, K’ imole wa l’oni; ‘Wo, Orun, ran s’ okunkun wa, K’o si le oru lo.
Read hymn : OJO ‘mole l’ eyiOJO ‘mole l’ eyi, K’ imole wa l’oni; ‘Wo, Orun, ran s’ okunkun wa, K’o si le oru lo.
Read hymn : OJO ‘mole l’ eyiOJO ‘simi at’ ayo Ojo inu didun, Etutu fun wahala, T’ o dara, t’ o si ndan!
Read hymn : OJO ‘simi at’ ayoOJU ko ti ri, eti ko ti gbo Ese t’ Olugbala pa f’ enia Re, Awon ti O feran, tin won feran Re, Ti nwon nfi ayo sin ninu ile Re.
Read hymn : OJU ko ti ri, eti ko ti gboOJ’ oni lo Jesu Baba, Boju Re w’ emi omo Re.
Read hymn : OJ’ oni loOKAN apata tuba, K’ eje Jesu mu o ro: Wo ara Re ti a gun, Wo bi eje ti bo O,
Read hymn : OKAN apata tubaOKAN are, ile kan mbe, Jina rere s’ aiye ise; Ile t’ ayida ko le de, Tani fe lo simi nibe?
Read hymn : OKAN are, ile kan mbeOKAN mi, odun kan ninu Aiye re koja lo; Eni ko le gbe ihin pe, Eyi le j’ opin mi.
Read hymn : OKAN mi, odun kan ninuOKAN mi, oju re tun ri Afemo ju ojo; Lekan si, korin, ohun mi S’ Oba t’ O je loke.
Read hymn : OKAN mi, oju re tun riOKAN mi, Oluwa ni, Jesu re ni, gb’ oro Re; Jesu nso, O mba o so, Pe, “Elese, ‘wo fe mi?”
Read hymn : OKAN mi, Oluwa niOKAN mi, sunmo ‘te anu, Nibi Jesu ngb’ ebe, F’ irele wole l’ ese Re, ‘Wo ko le gbe nibe.
Read hymn : OKAN mi, sunmo ‘te anuOKAN mi, tun rohin Enit anu Re, po, T’ ibinu Re ki ru Kankan, T’ o yara mu suru.
Read hymn : OKAN mi, tun rohinOKAN mi nsimi, Oluwa; Ngo dupe, ngo ko ‘rin, Okan mi r’ ibi asiri Ti ire ti nsun wa.
Read hymn : OKAN mi nsimi, Oluwa