OLUWA l’ O nso mi
OLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe?
Read hymn : OLUWA l’ O nso miOLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe?
Read hymn : OLUWA l’ O nso miOLUWA mbo aiye o mi Oke y’o sidi n’ipo won; At ‘irawo oju orun, Y’o mu imole won kuro.
Read hymn : OLUWA mbo aiye o miOLUWA mi, mo kepe O Ngo ku b’ O ko ran mi lowo; Jo, fi igbala Re fun mi Gbi mi bi mo ti ri.
Read hymn : OLUWA mi, mo kepe OOLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l’ emi o mo, L’ oro, l’ ero ati n’ ise.
Read hymn : OLUWA mi, mo njade loOLUWA mo gb’ ohun Re, Ti npe mi wa ‘do Re, Fun ‘wenumo n’nu eje Re T’o san ni Kalfari.
Read hymn : OLUWA mo gb’ ohun ReOLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni ObaOLUWA orun at’ aiye! Jesu, Omo ninu ara! Emi Mimo fun ‘toju wa! E gbo, ki E si gb’ eje wa.
Read hymn : OLUWA orun at’ aiyeOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin.
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funOLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re.
Read hymn : OLUWA sokaleOLUWA t’ o mo julo, K’ a wole l’ oruko Re; Ife Re ki ye titi, Kab’yesi Oba rere.
Read hymn : OLUWA t’ o mo juloOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiOLUWA wa mimo, Ti ogun orun nyin, Masai gbo wa; Kerubu, Serafu,
Read hymn : OLUWA wa mimo