A RE mu o okan re poruru
A RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu nikan.
Read hymn : A RE mu o okan re poruruA RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu nikan.
Read hymn : A RE mu o okan re poruruASAN n’ ireti t’ enia ko Le ori ise won: A bi won pel’ okan eri, Ebi si n’ iwa won.
Read hymn : ASAN n’ ireti t’ enia koASORO ile ‘bukun ni Ile didan, at’ ile ewa ‘Gbagbogbon l’ a nso t’ogo re; Y’o ti dun to lati de ‘be!
Read hymn : ASORO ile ‘bukun niATI gbo iro didun, Jesu le gba ni la, Ji ‘se na yi aiye ka, Jesu le gba ni la,
Read hymn : ATI gbo iro didunAWA nbebe fun ‘le wa, Ki Afrika ko pe; K’ Olorun Olodumare, Fi alafia fun u.
Read hymn : AWA nbebe fun ‘le waA WON eye n’ ife, Kolokolo n’ iho, enia n’ ile: Eda n’ ib’ isimi Sugbon Jesu ko r’ ibi gborile.
Read hymn : A WON eye n’ ifeAWON mimo! Ija nwon pin, Nwon segun aiye nikehin, Nwon ko fe ohun ija mo; Nwon da won si ese Jesu;
Read hymn : AWON mimo! Ija nwon pin“A YE si mbe!” ile Odagutan, Ewa ogo re npe o pe, “Ma bo”, Wole, wole, wole nisisiyi.
Read hymn : A YE si mbe!” ile OdagutanAYIN O, Oluranwo wa, T’ife Re wa bakanna lai, Owo ike en’t’ o bere, Ti o si pari odun wa.
Read hymn : AYIN O, Oluranwo waA YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re, Fun Jesu ti o ku to si lo soke
Read hymn : A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe ReAYO awon ti to, T’ o gb’ Olugbala gbo, T’o to isura nwon si oke Ahon ko le s’ adun
Read hymn : AYO awon ti toAYO b’ aiye: Oluwa de! K’ aiye gba Oba re; K’ okan gbogbo pes’ aye fun, Ki gbogb’ eda korin.
Read hymn : AYO b’ aiye: Oluwa de