AWON mimo! Ija nwon pin
First time here? Explore the hymn tools.
Verse 1
AWON mimo! Ija nwon pin,
Nwon segun aiye nikehin,
Nwon ko fe ohun ija mo;
Nwon da won si ese Jesu;
Awon mimo! Eni ‘bukun,
‘simi won mbe lese Jesu!
Verse 2
Awon mimo! irin won pin,
Nwon ko tun sure ije mo,
Are at’ isubu d’ opin,
Ota on eru ko si mo;
Awon mimo! eni ‘bukun,
‘Simi won dun n’ ile nla.
Verse 3
Awon mimo! ajo won pin,
Nwon gun s’ ebute ayo ni,
Nwon ko tun beru iji mo,
Tabi riru igbi okun;
Awon mimo! eni ‘bukun
L’ebute aabo ‘simi won.
Verse 4
Awon mimo! nwon nso ona,
‘Gbat’ ara won sun n’ iboji,
Tit’ igbala tin won y’o jinde
Lati ti ayo goke lo;
Enyin mimo! e ho f’ ayo;
Oluwa wa mbowa Kankan.
Verse 5
Olorun, Iwo l’ a nkepe,
Olugbala, ba wa bebe;
Emi Mimo, Oluto wa,
F’ ore-ofe fun wa d’opin;
K’ a le ba ‘won mimo simi
Ni Paradise pelu Re.
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.