SION yara, k’ o je ise giga re
SION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan segbe s’ inu okunkun.
Read hymn : SION yara, k’ o je ise giga reSION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan segbe s’ inu okunkun.
Read hymn : SION yara, k’ o je ise giga reJE ran orun kekere nibiti o nlo, Se ranlowo lati le okunkun l’ aiye, ‘Wo o ri b’ okunkun yio ti lo kuro, B’ iwo ba je ‘mole njojumo.
Read hymn : JE ran orun kekere nibiti o nloITAN kan wa f’ awon orile, Ti yio tun okan won se, Itan otito ti o si dun, Itan alafia on ‘mole,
Read hymn : ITAN kan wa f’ awon orileNGO je ‘mole fun Jesu, Ki ntan nigba gbogbo, Ki ntan s’ ibi to fe mi, Ki ntan l’ojojumo,
Read hymn : NGO je ‘mole fun JesuWA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun,
Read hymn : WA, obirin, e koA YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re, Fun Jesu ti o ku to si lo soke
Read hymn : A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe ReKristi lori agbelebu, Ti san gbogbo igbese mi, Ko si ohun miran t’ o le, Ma alafia didun na wa.
Read hymn : ORIN t’o dun wa s’okan miA RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu nikan.
Read hymn : A RE mu o okan re poruruB’O ti dun lati gba Jesu Gbo gege bi oro Re; K’ a simi lor’ ileri Re, Sa gbogbo l’ Olyuwa wi.
Read hymn : B’O ti dun lati gba JesuT’ IFE Jesu t’o wa mi, Gbat’ mo nu n’ ese; T’ ore ofe t’ o mu mi Pada bo sin’ agbo;
Read hymn : T’ IFE Jesu t’o wa miNWON duro fun ete kan Nwon gbo t’Olorun; Bola fun Olotito K’a nyin egbe Daniel –
Read hymn : NWON duro fun ete kanENIKAN se ise wura; On wa b’ ore nigba aini; Enikan ko orin ayo, Nmu sanma dan ni gbogb’ ojo.
Read hymn : ENIKAN se ise wura