WO! gbogbo ile okunkun
WO! gbogbo ile okunkun, Wo! okan mi, duro je; Gbogbo ileri ni o nso T’ ojo ayo t’o l’ ogo;
Read hymn : WO! gbogbo ile okunkunWO! gbogbo ile okunkun, Wo! okan mi, duro je; Gbogbo ileri ni o nso T’ ojo ayo t’o l’ ogo;
Read hymn : WO! gbogbo ile okunkunWO! Oluwa l’ awonsanma, O mbo l’ ogo’ l’ ola Re. Enit’ a pa fun elese Mbo pelu Angeli Re:
Read hymn : WO! Oluwa l’ awonsanmaWO, awon t’ o ‘so ala, Nwon duro leti odo, Nwon k’ ehin s’ aiye at’ esu, Nwon ntele Atebomi;
Read hymn : WO, awon t’ o ‘so alaWO b’ ikore tip o L’ otun l’ osi wa, Alagbase kere L’ ogba Oluwa,
Read hymn : WO b’ ikore tip oWO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo.
Read hymn : WO Imole! larin okun aiyeWO kakiri f’ enit’ o s’ alaini, R’ enia lowo loni! Bi ‘ranlowo na si tile kere, R’ enia lowo loni!
Read hymn : WO kakiri f’ enit’ o s’ alainiWO oju sanma ohun ni. Wo lila orun oro. Ji l’ oju orun, okan mi, Dide k’ o si ma sora;
Read hymn : WO oju sanma ohun niWO Oluwa oke, Ati abe ‘sanma; Mo do bale li ese Re, Mo nke fun anu Re.
Read hymn : WO Oluwa okeWO Ore okan ti nkanu! T’ O feran nwon titi d’ opin Eyi n’ ireti mi ro mo, Pe’ “‘Wo o be fun mi.”
Read hymn : WO Ore okan ti nkanuWO ti ngb’ adura igbagbo, O ki ogb’ okan lowo ‘ku T’ o gb’ ara re le O? Emi ko l’ abo fun ‘ra mi,
Read hymn : WO ti ngb’ adura igbagboWO t’ o nbebe f’ ota Re, L’ or’ igi agbelebu; Wipe “Fiji won Baba”, Jesu sanu fun wa.
Read hymn : WO t’ o nbebe f’ ota ReWO t’ O teriba nin’ odo Jordani, T’ O mokun n’nu ‘banuje wa, t’ O si ku T’ O jinde ninu okunkun sin’ ogo, T’ O si gba ‘joba ife awon Tire.
Read hymn : WO t’ O teriba nin’ odo Jordani