AYO kun okan wa loni
AYO kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso t’ ibi Re loni:
Read hymn : AYO kun okan wa loniAYO kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso t’ ibi Re loni:
Read hymn : AYO kun okan wa loniAYO omo anu ti to! T’ o mo idariji: O nwip’ aiye ki se ‘le mi, Mo nwa ‘le mi s’ orun
Read hymn : AYO omo anu ti toBABA, a f’ ara wa, S’ iso Re l’ ale yi; Da bobo wa, k’ O pa wa mo, Tit’ ile o fi mo.
Read hymn : BABA, a f’ ara waBABA, aniyan at’ eru Le su l’ ojo ola, Sugbon ‘foya ko le wo ‘bi; Tire l’ ojo oni.
Read hymn : BABA, aniyan at’ eruBABA, a tun pade l’ oko Jesu, A si wa teriba lab’ ese Re; Si O l’ a tun fe gb’ ohun wa s’ oke Lati wa anu, lati ko ‘rin ‘yin.
Read hymn : BABA, a tun pade l’ oko JesuBABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa:
Read hymn : BABA, je nya odun yiBABA, mo n’ owo mi si O; Nko mo ‘ranwo miran: Bi O ba kuro lodo mi, A! nibo ni ngo lo?
Read hymn : BABA, mo n’ owo mi si OBABA, Omo, on Emi, Eni Metalokan lai, Jo, masai dabobo wa, K’ a le ri ‘mole ola.
Read hymn : BABA, Omo, on EmiBABA jowo gb’ adura wa, Bi a tin lo loju omi; Iwo ma je ebute wa, Si ma je ile isimi.
Read hymn : BABA jowo gb’ adura waBABA ma yi oju kuro Fun emi otosi; Ti np’ ohunrere ese mi N’ iwaju ite Re.
Read hymn : BABA ma yi oju kuroBABA mi, ‘gba mo nsako lo, Kuro l’ ona Re l’ aiye yi; Ko mi kin le bayi pe, Se ‘fe Tire.
Read hymn : BABA mi, ‘gba mo nsako loBABA orun! Emi fe wa N’ iwa mimo, l’ ododo; Sugbon ife eran’-ara Ntan mi je nigbagbogbo.
Read hymn : BABA orun! Emi fe wa