EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de
EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole, Eyini yio j’ ogo fun mi,
Read hymn : EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de643 hymns
EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole, Eyini yio j’ ogo fun mi,
Read hymn : EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio deEMI Mimo, ‘Dada orun, Wa li agbara Re; K’ o da ina ife mimo, Si okan tutu wa.
Read hymn : EMI Mimo, ‘Dada orunEMI orun, gb’ adura wa, Wa gbe ‘nu ile yi, Sokale pel’ agbara Re, Wa, Emi Mimo wa.
Read hymn : EMI orun, gb’ adura waEMI wa ba w ape, L’ ojo isimi yi; Laisi Re awa ko le sin, A ko le gb’ adura.
Read hymn : EMI wa ba w apeEMI ‘bukun, bi afefe, Ni nfe sibit’ o wu; Awon, t’ iji re lu, bawo L’ okan won ti yo to!
Read hymn : EMI ‘bukun, bi afefeEMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi.
Read hymn : EMI, Olore ofeENDE, korin Mose Ati t’ Odagutan; Ji, gbogbo okan at’ ahon , K’ e yin Olugbala.
Read hymn : ENDE, korin MoseENI ba gbekel’ Olorun, L’ abo l’ orun at’ aiye: Eni ba f’ ife wo Jesu, Ko s’ eru ti damu re.
Read hymn : ENI ba gbekel’ OlorunENI ‘subu se le Mo loju Olorun, Bi O ba tele pipe wa Ao subu lab’ egbe.
Read hymn : ENI ‘subu se leENIKAN mbe t’ O feran wa, A! O fe wa! Ife Re ju t’ iyekan lo, A! O fe wa!
Read hymn : ENIKAN mbe t’ O feran waENIKAN se ise wura; On wa b’ ore nigba aini; Enikan ko orin ayo, Nmu sanma dan ni gbogb’ ojo.
Read hymn : ENIKAN se ise wuraENIT’ o ba gbo, kigbe iro na, Ran ihinrere na si gbogbo aiye Tan ihin na ka ‘bi gbogbo t’ enia wa, “Enit’ o ba fe le wa?
Read hymn : ENIT’ o ba gbo, kigbe iro naENYIN Angel’ l’ orun ogo To yi gbogbo aiye ka, E ti ko ‘rin dida aiye, E so t’ ibi Messia,
Read hymn : ENYIN Angel’ l’ orun ogoENYIN enia Olorun, Mo ti kiri aiye ka, To ‘pa ese on ‘kanu, Nko r’ itunu n’ ibikan.
Read hymn : ENYIN enia OlorunENYIN ero, nibo l’e nlo T’ enyin t’ opa lowo nyin?” A nrin ajo mimo kan lo, Nipa ase Oba wa,
Read hymn : ENYIN ero, nibo l’e nloENYIN iran Adam, Da ohun orin po, Mo t’ orun at’ aiye, Lati yin Eleda;
Read hymn : ENYIN iran AdamENYIN omo oku, T’ o wa ninu ese, Gb’ ohun ihinrere, Jesu ranse si iyin.
Read hymn : ENYIN omo okuENYIN ti nkoja Ya sodo Jesu: O s’ asan fun nyin bi, bi Jesu ba ku?
Read hymn : ENYIN ti nkojaENYIN t’ e fe Oluwa, E fi ayo nyin han, E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun,
Read hymn : ENYIN t’ e fe OluwaENYIN t’e f’oluwa, T’o mo ‘pa Re, e wa, E dapo n.isokan, Lati yin ore Re;
Read hymn : ENYIN t’e f’oluwaEREDI irokeke yi Ti enia ti now koja? ‘Jojumo n’ iwojopo na, Eredi re tin won nse be?
Read hymn : EREDI irokeke yiEREDI iwa s’ aiye mi? ‘Tori kil’ a bi mi? Gbogb’ ohun l’ aiye l’ o n’ idi, Kil’ a ha da mi fun?
Read hymn : EREDI iwa s’ aiye miERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri.
Read hymn : ERO didun kan nsoESE mi po bi irawo, B’ iyanrin let’ okun; Sugbon iyonu Olorun, O papoju be lo.
Read hymn : ESE mi po bi irawo