BABA orun, nin’ oro Re
BABA orun, nin’ oro Re Ni ogo orun ntan; Titi lai l’ a o ma sin O, Fun Bibeli mimo.
Read hymn : BABA orun, nin’ oro ReBABA orun, nin’ oro Re Ni ogo orun ntan; Titi lai l’ a o ma sin O, Fun Bibeli mimo.
Read hymn : BABA orun, nin’ oro ReBABA orun, ti ife Re B’ okan wa, wa irapada, A teriba niwaju Re, Jo fun wa n’ idariji Re.
Read hymn : BABA orun, ti ife ReBABA wa Olodumare, ‘Wo t’ o kawo igbi omi, ‘Wo t’ o ti f’ ipo okun fun. Ti ko le ri ibe koja;
Read hymn : BABA wa OlodumareBABA wa ti o mbe l’ orun, Owo l’ oruko Re, ‘Joba Re de, ife Re ni K’ a se bi ti orun.
Read hymn : BABA wa ti o mbe l’ orunBAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,”
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBELESE s’owo po, Ti nwon nde s’Oluwa, Dimo si Kristi Re, Lati gan Oba na,
Read hymn : BELESE s’owo poBENI, O bikita fun mi, Pelu ike bi t’ egbon ; Beni, eru at’ ifoiya, Gbogbo re l’ O mba mi pin.
Read hymn : BENI, O bikita fun miBI agbonrin ti nmi hele, S’ ipa odo omi; Beni okan mi nmi si O, Iwo Olorun mi.
Read hymn : BI agbonrin ti nmi heleBI a ti f’ okan wa fun O Nip’ ase mimo Re, Ran s’ or’ omi, ‘Daba orun, F’ edidi t’ eje na.
Read hymn : BI a ti f’ okan wa fun OBIBELI mimo t’ orun Owon isura t’ emi! ‘Wo ti nwi bi mo ti ri, ‘Wo ti nso bi mo ti wa.
Read hymn : BIBELI mimo t’ orunBIBEL’ iwe aiyeraiye Tani le ridi re? Tani le so idide re? Tani le m’ opin re?
Read hymn : BIBEL’ iwe aiyeraiyeBI Jesu ba fe mi, Bi mo ba je Tire, Nko ko ohun t’ ota le ro, Bi nwon tile n’ ipa.
Read hymn : BI Jesu ba fe mi.