BI mo egbarun ebun
BI mo egbarun ebun, Ngo di mo Jesu ti a pa, Y’o je ipile mi; ‘Tori ko s’ ipile miran,
Read hymn : BI mo egbarun ebunBI mo egbarun ebun, Ngo di mo Jesu ti a pa, Y’o je ipile mi; ‘Tori ko s’ ipile miran,
Read hymn : BI mo egbarun ebunBI mo ti ri – laisawawi, Sugbon nitori eje Re, B’O si ti pe mi pe ki nwa – Olugbala, mo de.
Read hymn : BI mo ti ri – laisawawiBI osun gbege eti ‘do, Tutu minimini; B’ igbo dudu eti omi, B’ itanna ipa ‘do.
Read hymn : BI osun gbege eti ‘doBI o ti ri laisi ami Ife, ayo, tab’ ore kan, T’ o ye fun ibugbe orun, Elebi, ma bow a.
Read hymn : BI o ti ri laisi amiBO ti dun to l’ oj’ owo yi, Ojo t’ o dara ju, Ki a pa ‘ronu aiye Ki a pa ‘ronu nkan t’ orun!
Read hymn : BO ti dun to l’ oj’ owo yiBUKUN ni fun ohun, T’ o de wa po n’nu ‘fe; Idapo awon olufe, Dabi ijo t’ orun.
Read hymn : BUKUN ni fun ohunB’AIYE mi kun fun ‘banuje, O dara, o te mi l’orun; Laikun mo nreti ipe Re, Gbogbo nkan ni emi ntoro.
Read hymn : B’AIYE mi kun fun ‘banujeB’ AWON ara igbani Ti f’ ayo ri ‘rawo na; Bi nwon ti f’ inu didun Tele ‘mole didan re;
Read hymn : B’ AWON ara igbaniB’ AYO aiye ti j’ asan to! Didara won ko pe! Ko s’ ayo ti ko l’ ororo, Adun re je ‘dekun.
Read hymn : B’ AYO aiye ti j’ asan toB’ENU mi dun bi t’ awon ju, T’ ede mi ta t’ angeli yo; Laisi ife mo dab’ ide, Ti ohun re nhan ni l’ eti.
Read hymn : B’ENU mi dun bi t’ awon juB’ IFE Olugbala ti dun to! Bi t’ okun iwon re tayo; Ewa didara re julo ni Pe o to tile ndun si ni fun mi,
Read hymn : B’ IFE Olugbala ti dun toB’ ODO ti nyara san lo, Li ona gboro re, Ti omi re nja titi, T’ o nsare lo s’ okun,
Read hymn : B’ ODO ti nyara san lo