GBA alare nwa sinmi
GBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re;
Read hymn : GBA alare nwa sinmiGBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re;
Read hymn : GBA alare nwa sinmiGBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aaye Nn’ orin at’adura, ale; N’ alo at’ ife eba ina, Ibagbe re si wa yi wa ka,
Read hymn : GBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aayeGBA Jesu ba de lati pin ere, B’ o j’ osan tabi l’ oru, Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona, Pel’ atupa wa tin tan?
Read hymn : GBA Jesu ba de lati pin ereGBA mo le ka oye mi re, Ni ibugbe l’oke; Mo dagbere f’eru gbogbo, Mo n’omije mi nu.
Read hymn : GBA mo le ka oye mi reGBAT, a b’Oluwa rin N’nu ‘mole oro Re Ona wa yi o ti l’ogo to! ‘Gbat’ a ba nse f’e Re
Read hymn : GBAT, a b’Oluwa rinGBATI ipe Oluwa ba dun T’ akoko ba si pin, T’ imole owuro mimo ntan lailai; Gbat’ awon t’ a ti gbala,
Read hymn : GBATI ipe Oluwa ba dunGBATI mo ri agbelebu, Ti a kan Oba-ogo mo, Mo ka gbogbo oro s’ ofo, Mo kegan gbogbo ogo mi.
Read hymn : GBATI mo ri agbelebu,GBATI Samueli ji To ‘igb’ ohun Eleda Ni gbolohun kokan, Ayo re ti po to
Read hymn : GBATI Samueli jiGBATI ‘ji goke l’ ona re, T’ o f’ aniyan kun okan mi, N’ gbekele w’ oke, wipe, “Mo mo p’ Oluwa wa n’ tosi.”
Read hymn : GBATI ‘ji goke l’ ona reGBAT’ aiye yi ba koja, Ti orun re ba si wo, Ti a ba wo ‘nu ogo, T’ a bojuwo ehin wa;
Read hymn : GBAT’ aiye yi ba kojaGBAT’ a kun fun ‘banuje, Gb’ omije nsan l’ oju wa, Gbat’ a nsokun, t’ a nsofo, Olugbala, gbo ti wa.
Read hymn : GBAT’ a kun fun ‘banuje,GBAT’ emi re ba fo lo, T’ iku ba siji bo o; ‘Gbati sa re ba pari, Elese n’ bo l’ o yo si?
Read hymn : GBAT’ emi re ba fo loGBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe!
Read hymn : GBAT’ O ba de, gbat’ O ba deGBAT’ oju mi ba se peki ‘Mole to se n’ ila orun, Orun ododo masai ran Ase anu re s’ ori mi,
Read hymn : GBAT’ oju mi ba se pekiGBAT’ okan are fe ‘simi, T’ o nwa Olorun re, B’ o ti dun to lati r’ ale T’ o pin ose lala.
Read hymn : GBAT’ okan are fe ‘simiGBA t’ Olugbala w’ aiye, Anu j’ oba l’ okan Re, O nfi ibakedun han K’ O si gan enikeni.
Read hymn : GBA t’ Olugbala w’ aiyeGBA ‘Wo Onidajo ba de Lati m’ awon Tire lo ‘le, Ngo ha wa l’ arin won? Ao ha r’ ekolo lasan yi,
Read hymn : GBA ‘Wo Onidajo ba deGBEKELE ojojumo, ‘Gbekele ninu iji, B’ igbgbo tile kere, Ki nsa gbekele Jesu.
Read hymn : GBEKELE ojojumoGBEKELE onigbagbo, B’ ija na tile pe, Sibe iwo yio segun, Olorun ja fun o.
Read hymn : GBEKELE onigbagboGBEKE re le Oluwa, F’ oro Re s’ agbara re; Y’o duro ti o lailai, B’ orun tile koja lo.
Read hymn : GBEKE re le OluwaGBO! Orin ti Jubili, O dabi sisan ara; Tabi bi kikun okun, Gbat’ igbi re ba nlu ‘le
Read hymn : GBO! Orin ti JubiliGBO-GB’ ogo iyin ola, Fun O oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun!
Read hymn : GBO-GB’ ogo iyin olaGBO ase ti Jesu pa, “Lo wasu ‘hinrere Mi, Enikeni t’ o gbagbo, T’ a si tebomi, yio la.”
Read hymn : GBO ase ti Jesu paGBO eda orun nkorin, “Ogo fun Oba t’ a bi.” “Alafia l’ aiye yi,” Olorun ba wa laja,
Read hymn : GBO eda orun nkorin