Yoruba Baptist Hymns
OLUWA, ojo t’ O fun wa pin
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
OLUWA, ojo t’ O fun wa pin
Okunkun si de l’ ase Re
‘Wo l’ a korin owuro wa si,
Iyin Re y’o m’ale wa dun.
Verse 2
A dupe ti Ijo Re ko nsun,
B’ aiye ti nyi lo s’ imole,
O si nsona ni gbogbo aiye,
Ko si simi t’ osan-t’ oru.
Verse 3
B’ ile si tin mo lojojumo
Ni orile at’ ekusu,
Ohun adura ko dake ri,
Be l’ orin iyin ko dekun.
Verse 4
Orun t’ o wo fun wa, si ti la
S’ awon eda iwo-orun,
Nigbakugba lie nu si nso
Ise ‘yanu Re di mimo.
Verse 5
Be, Oluwa, lai n’ijoba Re,
Ko dabi ijoba aiye;
O duro, o sin se akoso
Tit’ eda Re o juba Re.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/oluwa-ojo-t-o-fun-wa-pin/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.