YBH 10

OLUWA po! Ogun orun wole fun

1. OLUWA po! Ogun orun wole fun,
Ati enyin t’ o nrin l’ aiye.
E yon in orin mimo niwaju Re,
Ki e si yin Eleda yin.

2. Oluwa po! Titobi Re si l’ ogo,
E yin lat’ ile de ile,
B’ Asegun lor’ iku, ese at’ egbe,
O njoba, O npase lailai.

3. Oluwa po! Anu Re si tip o to
Enyin mimo gbe harpu yin,
E fi ohun ol’ okun wura korin
S’ Oluwa, Oba ‘won Oba.

(Visited 378 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you