YBH 12

IRANSE, e fonrere Oba nyin

1. IRANSE, e fonrere Oba nyin,
E si tan ‘hin oruko nla Re ka,
Gbe oruko Asegun ti Jesu ga,
Ijoba Re l’ ogo, o ka gbogb’ aiye.

2. O npase l’ oke, Olugbala nla,
Sibe ara Re ko jina si wa,
Awon ijo nla y’o korin segun Re,
Nwon o si fun Jesu l’ ogo igbala.

3. Ogo fun Oba t’ O wa lor’ ite,
Egb’ ohun s’ oke, fun Jesu ‘lola,
Awon angeli nfi iyin Jesu han,
Nwon d’ oju bo ‘le nwon nsin Od’ – agutan.

(Visited 206 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you