YBH 13

GBOGBO eda dapo

1. GBOGBO eda dapo,
E jo yin Oluwa,
E pa ohun nyin po
Lati fe oro na;
K’ ife da orin open la,
Ki gbogbo eda k’ o si gbe.

2. Sugbon o ye k’ iyin
T’ enia ga julo,
Ki okan idupe
Fi itara gbona
Ki ohun ope yin le ‘ke,
Enyin t’ a fun l’ opo ‘bukun.

3. Mi sinu okan mi,
Oluwa Olore,
‘Gbana ngo f’ irele,
B’ awon egbe korin.
Ife Re le la mi l’ ohun
Le fi orin ‘yin si mi l’ enu.

(Visited 440 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you