YBH 14

GBOGBO eda labe orun

1. GBOGBO eda labe orun.
E fi iyin fun Eleda wa:
Ki gbogbo orile-ede
Ko Olugbala wa l’ orin.

2. Titi l’ anu Re, Oluwa.
Oto Re si duro lailai
Iyin Re y’o tan kakiri.
D’ igba t’ orun ki y’o wo mo.

(Visited 338 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you