JE ki gbogbo eti ko gbo,
Ki gbogbo okan yo,
Ipe ‘hinrere nfi ohun
Ifanimora dun.
2. Enyin okan tie bi npa,
T’o nf’ategun s’onje,
T’o nja lasan, lati nkan
Aiye b’okan ebi.
3. Ogbon ailopin ti pese
Ase isokanji,
O si npe ebi inu re
Wa to ase na wo.
4. Enyin t’o npongbe om’ iye
Ti ns’ ofo, t’o si nku,
Nibi l’ e le fi orisun
Ti ki gbe p’ ongbe nyin.
5. Lekun ayo, ihinrere
Si le losan, l’ oru
Oluwa, a wa ebun wa,
Le aini wa kuro.
(Visited 170 times, 1 visits today)