YBH 199

WALEJO kan lenu ona

1. WALEJO kan lenu ona:
O nkankun je, O ti nkan ri;
O ti duro pe, O nduro;
Ko s’ ore t’ o je ba lo be.

2. ‘Duro ife! a, O nduro,
Okan Re yo, owo Re na:
Iseun nla! Ani s’ awon
Ota Re l’ O f’ iru yi han.

3. Dide, k’ okan im’ ore so,
Le Esu ota re jade;
At’ ese t’ o de okan re,
Je k’ Alejo orun wo le.

4. F’ ayo ko, Omo Alade!
K’ ijoba Re tun ma po si!
S’ ilekun paya, okan ‘fe;
Ki gbogb aiye je ‘joba Re.

(Visited 149 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you