1. mJE k’ agb’ oju ayo s’ oke
Si agbala orun,
K’ a yo lati ri Baba wa
Lori ite ife.
2. Wa, je k’ a wole l’ ese Re,
K’ a sunmo Oluwa,
Angeli ina tab’ ida
Ki’ so ‘bujoko Re.
3. Jesu s’ ilekun ‘lafia
T’ ayo orun sile,
K’ orin iyin wag a s’ oke
De ‘te t’ o l’ agbara.
4. A m’ opo ope wa fun O,
Alagbawi t’ oke;
Ogo fun Oba t’ o w alai,
T’o pa ‘binu Re mo.
(Visited 955 times, 1 visits today)