1. GBEKELE ojojumo,
‘Gbekele ninu iji,
B’ igbgbo tile kere,
Ki nsa gbekele Jesu.
B’ iseju t info Kankan,
Bi ojo nkoja lo,
Ohunkohun t’ o le de,
Gbekele Jesu nikan.
2. Emi Re nmole pupo,
Sinu okan osi mi,
B’ O ban to mi nk’y’o subu,
Ki nsa gbekele Jesu.
3. Ki nkorin b’ ona mi to,
Gbadura gbat’ ona su,
Ki nke pe ninu ‘danwo,
Gbekele Jesu nikan.
4. Ki ngbekele d’ oju ‘ku,
Titi aiye yio koja,
Titi ngo fi de orun,
Gbekele Jesu nikan.
(Visited 1,795 times, 1 visits today)