YBH 250

GBEKELE onigbagbo

1. GBEKELE onigbagbo,
B’ ija na tile pe,
Sibe iwo yio segun,
Olorun ja fun o.
Sa gbekele!
B’ okunkun tile su:
Sa gbekele!
Ile fere mo na.

2. Gbekele! ewu ma mbo,
Idanwo wa n’tosi;
Ninu gbogb’ ewu aiye,
On yio t’ oko re.

3. Oluwa le gba wa la,
Ore otito ni;
Gbekele onigbagbo,
Gbekele de opin.

(Visited 12,925 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you