1. F’ORUKO Jesu s’ okan re
Om’ egbe on ‘banuje;
Yio fun o l’ayo oun ‘tunu
Gbee wo lo s’ibi gbogbo
Ooko ‘re… ti dun to!
‘Ret’ aiye, ayo orun
Ooko ‘re… ti dun to!
‘Ret’ aiye, ayo orun
2. Mu ooko Jesu titi lai
B’abo laarin idekun
Bi ‘danwo ba si yi o ka,
F’ ooko Mimo naa gbadu’a
3. A Oruko ‘re ti Jesu
Bo ti mu k’ emi wa yo
‘Gbat’ apa ‘fe Re ba gba wa
T’ ahon wa si korin Re
4. Ao juba oruko Jesu
Ao wole lie se Re
Oba orun yio de l’ade
‘Gbat’ ajo wa ba pari.
(Visited 813 times, 1 visits today)