YBH 262

KO si ewa nibikan ti

1. KO si ewa nibikan ti
Mo le fi we ti Krist’:
Ohun t’ oku, Oluwa, ni
K’ a je ‘kan pelu Re.

2. Mu imo iku, ife Re
Wa sinu okan mi:
F’ ara Re fun mi n’toriti
‘Wo nikan ni mo fe.

3. Ara Re nikan l’ o to mu
Itunu mi pada;
Nko le bere, be O ko le
Fun mi ju ‘ra Re lo.

4. Ko mi lati lo ohun ti
Ki se ‘fe Re sile;
Oloro ni mo je n’n’ ayo
B’ Iwo ba je t’ emi.

(Visited 403 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you