1. IFE mi s’ ibi ti wa pe,
Lai beru itiju,
Titi mo fi r’ ohun titun,
Ti o da mi duro.
2. Mo r’ enikan nro lor’ igi,
N’ irora on eje,
O te oju are mo mi,
Bi mo ti duo ti.
3. A, titi ngo fi ku, nko je
Gbagbe wiw’oju na,
B’ eni nwipe, emi l’o se
Sugbon ko s’ oro kan.
4. Okan mi si gba ebi na,
O nmu mi banuje,
Mo ri p’ ese mi l’ o pa A
L’ o kan m’ agbelebu.
5. O tun mi wo, oju Re ni,
“Mo dari re ji o,
Eje yi l’ o san ‘gbese re,
Mo ku, k’ o ba le ye.”
(Visited 198 times, 1 visits today)