1. JESU wipe k’ a ma sora
Ni wakati gbogbo,
O si nf’ emi isoji fun
Awon t’ o mbere re.
2. Jesu wipe ka ma gb’ adua
K’ a ma ja lais’ are;
Oluwa, je k’ a gbo ‘pe Re
Igboran n’ iye wa.
3. Jesu wipe k’ a ma so ‘ra
Akoko na de tan,
Ti yio pe wa kuro l’ aiye,
S’ ibugbe wa orun.
4. Jesu, a fe ma gb’ adura,
A fe ma gb’ ohun Re,
A fe ma rin n’nu ‘lana Re,
Sib’ ayo ailopin.
(Visited 688 times, 1 visits today)