1. JESU np’ enia Re
S’ ori tabili Re,
Nibi l’ awon t’ a dariji
Nb’ Oluwa won dapo.
2. Wain at’ akara yi,
L’ o nm’ okan wa soji,
N’ idapo pel’ Oluwa wa,
At’ ere n’nu ‘ku Re.
3. K’ a d’ agbara wa po
Lati yin ‘ruko Re;
K’ ife mimo kun gbogb’ okan,
Ki gbogb’ ohun je ‘yin.
(Visited 180 times, 1 visits today)