1. IFE orun! alailegbe!
N’nu ase mimo yi,
Ogo re kun, ‘mole re po,
Ti ntan iye jade.
2. Iku on eje ‘yebiye,
T’ a ta sile fun wa
Fun ‘wenum’ okan ese wa
Ninu eb gbogbo.
3. Majemu ‘ye, t’ alaifia
T’ a fi eje pari!
Nihin l’ a fi gbogbo ebun
Or’ ofe han ‘gbagbo.
4. Jesu, a teriba fun O,
‘Reti at’ Iye wa,
A si nf’ ope on ‘banuje
Ro t’ iku ife Re.
5. A! t’ a ba ko fe Re pipe
Si aiya gbogbo wa;
K’ aiye at’ ese male bo
Agbara ogo re.
(Visited 384 times, 1 visits today)