YBH 395

JESU t’ asia Re bow a

1. JESU t’ asia Re bow a,
O f’ onje m’ okan way o;
O te ase siwaju wa,
T’ a f’ eran ara Re se.

2. Nihin l’ a r’ ifiji ese,
B’ a ti now Od’-agutan;
Gbogb’ ero wa si je t’ orun,
Ete wa si kun fun ‘yin.

3. Ninu aisimi ironu,
Sibe okan wa now O,
Tit’ ao fi r’ ekun ‘gbala Re,
T’ ao si fi ri ogo Re.

(Visited 243 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you