1. JESU a w’ odo Re
L’ ojo Re mimo yi;
To wa wa ba wa ti pejo,
Si ko wa fun ‘ra Re.
2. Dari ese ji wa
Fun wa l’ Emi Mimo
Si ko wa ka lo aiye wa,
K’ a le ye ‘bugbe Re.
3. F’ ife kun aiya wa
Bukun oluko wa;
K’ awa at’ awon le pade,
Niwaju Re l’ oke.
(Visited 792 times, 1 visits today)