YBH 561

B’ IFE Olugbala ti dun to

1. B’ IFE Olugbala ti dun to!
Bi t’ okun iwon re tayo;
Ewa didara re julo ni
Pe o to tile ndun si ni fun mi,

Refrain
Ndun si, ndun si ni fun mi,
O ndara lojojumo,
A! b’ ife yanu Olugbala,
Ti ndara si ni gbogb’ ona mi.

2. Mo mo p’ o wa lodo mi titi!
Aiyeraiye ni yio fi;
Giga ijinle anu Re,
At’ ailopin ife nla Re han.

Refrain
Ndun si, ndun si ni fun mi,
O ndara lojojumo,
A! b’ ife yanu Olugbala,
Ti ndara si ni gbogb’ ona mi

3. Nibikibi emi o tele,
Nin’ ayo tab’ ibanuje;
Bi o tile se ninu ina,
Oluwa, k’ a se ife nla Re.

Refrain
Ndun si, ndun si ni fun mi,
O ndara lojojumo,
A! b’ ife yanu Olugbala,
Ti ndara si ni gbogb’ ona mi.

4. Lojo kan ngo ri lojukoju,
Bi ayo na y’ o ti po to;
Ti ngo mo pe ife Re owon,
Y’o ma dun si fun mi titi lai!

Refrain
Ndun si, ndun si ni fun mi,
O ndara lojojumo,
A! b’ ife yanu Olugbala,
Ti ndara si ni gbogb’ ona mi.

(Visited 527 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you