YBH 652

NGO ha ku ni owo ofo

1. NGO ha ku ni owo ofo,
Ki mba oluwa mi be
Ko ti fun u n’ise ojo kan,
Ikogun fun On ko si.

Refrain
Ngo ha ku ni owo ofo
Ngo ha r’ Oluwa mi be
Ko si eso kan l’ owo mi
Ngo ha ku l’ owo ofo.

2. Iku ko lo deruba mi
‘Tori Jesu ngba mi la,
Ki mba On ni owo ofo
Iro yi nb’okan mi je.

Refrain
Ngo ha ku ni owo ofo
Ngo ha r’ Oluwa mi be
Ko si eso kan l’ owo mi
Ngo ha ku l’ owo ofo.

3. A! Akoko ti mo sonu
Nba le pe e pada,
Nba fi i fun Oluwa mi
T’Ife Re ni mo fe se.

Refrain
Ngo ha ku ni owo ofo
Ngo ha r’ Oluwa mi be
Ko si eso kan l’ owo mi
Ngo ha ku l’ owo ofo.

4. Eni mimo f’itara ji,
Dide, sise, l’ojo yi,
Ki igbe aiye re to tan,
So eso fun Oluwa –

Refrain
Ngo ha ku ni owo ofo
Ngo ha r’ Oluwa mi be
Ko si eso kan l’ owo mi
Ngo ha ku l’ owo ofo.

(Visited 1,657 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you