YBH 573

GBA Jesu ba de lati pin ere

1. GBA Jesu ba de lati pin ere,
B’ o j’ osan tabi l’ oru,
Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona,
Pel’ atupa wa tin tan?

Refrain
A le wip a mura tan ara,
Lati lo s’ ile didan?
Yio ha ba wa nibit’ a gbe ns’ ona?
Duro, tit’ Oluwa yio fi de?

2. Bi l’ owuro li afemojumo
Ni yio pew a l’ okankan;
Gbat’ a f’ Oluwa l’ ebun wa pada,
Yio ha dahun pe, “O seun?”

Refrain
A le wip a mura tan ara,
Lati lo s’ ile didan?
Yio ha ba wa nibit’ a gbe ns’ ona?
Duro, tit’ Oluwa yio fi de?

3. A s’ oto ninu liana Re,
Ti sa ipa wa gbogbo,
Bi okan wa ko bad a wa l’ ebi,
A o n’ isimi ogo.

Refrain
A le wip a mura tan ara,
Lati lo s’ ile didan?
Yio ha ba wa nibit’ a gbe ns’ ona?
Duro, tit’ Oluwa yio fi de?

4. Ibukun ni fun awon ti ns’ ona,
Nwon o pin nin’ ogo Re,
Bi O ba de l’ osan tabi l’ oru,
Yio ha ba wa n’ isona?

Refrain
A le wip a mura tan ara,
Lati lo s’ ile didan?
Yio ha ba wa nibit’ a gbe ns’ ona?
Duro, tit’ Oluwa yio fi de?

(Visited 4,009 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you