YBH 606

ONTO mi lo iro ‘bukun

1. ONTO mi lo iro ‘bukun,
Oro t’ orun tu mi ninu,
Ohun ti o wu kemi se
Sibe Olorun nto mi lo.

Refrain
Onto mi lo, Onto mi lo,
Owo Re l’ O fi nto mi lo,
L’ otito ni mo fe te le E
Nitoriti Onto mi lo.

2. Nigbamiran t’ iponju wa,
Nigbamiran l’ ogba Eden
L’ eba odo l’ okun ponju,
Sibe Olorun nto mi lo.

Refrain
Onto mi lo, Onto mi lo,
Owo Re l’ O fi nto mi lo,
L’ otito ni mo fe te le E
Nitoriti Onto mi lo.

3. Oluwa mo d’ owo Re mu
Nko ni kun nko ni banuje,
F’ ohun yow u ti mo le ri
Niwon t’ Olorun mi nto mi.

Refrain
Onto mi lo, Onto mi lo,
Owo Re l’ O fi nto mi lo,
L’ otito ni mo fe te le E
Nitoriti Onto mi lo.

4. Nigba ‘se mi l’ aiye ba pin,
T’ or’-ofe Re fun mi n’isegun,
Emi ko ni beru iku,
Niwon t’ Olorun mi nto mi.

Refrain
Onto mi lo, Onto mi lo,
Owo Re l’ O fi nto mi lo,
L’ otito ni mo fe te le E
Nitoriti Onto mi lo.

(Visited 4,387 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you