YBH 610

A KO ni ‘bugbe kan nihin

1. A KO ni ‘bugbe kan nihin,
Onile e roar yanran;
B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet,
Ese mefa ni busun wa.

2. A ko ni ‘bugbe kan nihin,
Or’ aiye fowoba fi le
Ni horiho la sa w’ aiye
Ni horiho lao pada lo.

3. A ko ni ‘bugbe kan nihin
O ko gbagbo p’ ajo l’ o wa?
Lo wo ‘boji w’ awon to sun,
Awon ni nwon de ‘bi simi.

(Visited 209 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you