YBH 609

JESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘le

1. JESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘le
O npe loni, o npe loni!
Ese t’ o fi ko ife Re sile,
T’ o sako jinna rere?

Refrain
O npe loni
O npe loni
Jesu npe jeje, O npe jeje, gbo ipe Re.

2. Jesu npe alare fun isimi –
O npe loni, o npe loni!
Gb’ eru re to O wa, yio bukun
Ki yio le o pada.

Refrain
O npe loni
O npe loni
Jesu npe jeje, O npe jeje, gbo ipe Re.

3. Wa nisiyi, Jesu nduro de o!
Nduro loni, nduro loni!
F’ irele gb’ ese re sab’ ese Re
Wa, mase tun duro mo.

Refrain
O npe loni
O npe loni
Jesu npe jeje, O npe jeje, gbo ipe Re.

(Visited 387 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you