1. ETUN won ko fun mi ki ngbo
Oro ‘yanu t’ Iye!
Je ki nsi tun ewa won ri,
Oro ‘yanu t’ Iye,
Oro iye at’ ewa, ti mko mi n’ igbagbo!
Oro didun! Oro ‘yanu
Oro ‘yanu t’ Iye.
2. Kristi nikan lo fi fun ni
Oro ‘yanu t’ Iye!
Elese gbo ‘pe ife na
Oro ‘yanu t’ Iye,
L’ ofe la fifun wa, ko le to wa s’orun
3. Gbo ohun ihinrere na,
Oro ‘yanu t’ Iye!
F’ igbala lo gbogbo enia
Oro ‘yanu t’ Iye,
Jesu Olugbala, we wa mo titi lai!
Oro didun! Oro ‘yanu!
Oro ‘yanu t’ Iye.
(Visited 687 times, 1 visits today)