1. MO fi gbogbo re fun Jesu
Patapata laiku kan;
Ngo ma fe ngo si gbekele,
Ngo si ma ba gbe titi.
Refrain
Mo fi gbogbo re,
Mo fi gbogbo re,
Fun O Olugbala mi ni
Mo fi won sile.
2. Mo fi gbogbo re fun Jesu ;
Mo si wole lese Re;
Mo fi afe aiye sile
Jesu jo gba mi wayi.
Refrain
Mo fi gbogbo re,
Mo fi gbogbo re,
Fun O Olugbala mi ni
Mo fi won sile.
3. Mo fi gbogbo re fun Jesu,
Jesu se mi ni tire;
Jek’ Emi Mimo s’ eleri
P’emi tire, ‘wo t’emi.
Refrain
Mo fi gbogbo re,
Mo fi gbogbo re,
Fun O Olugbala mi ni
Mo fi won sile.
4. Mo fi gbogbo re fun Jesu
Mo f’ ara mi f’ Oluwa;
F’ ife at’ agbara kun mi,
Si fun mi n’ ibukun Re.
Refrain
Mo fi gbogbo re,
Mo fi gbogbo re,
Fun O Olugbala mi ni
Mo fi won sile.
5. Mo fi gbogbo re fun Jesu,
Okan mi ngbona wayi;
A! ayo igbala kikun!
Ogo ni f’ Oruko Re.
Refrain
Mo fi gbogbo re,
Mo fi gbogbo re,
Fun O Olugbala mi ni
Mo fi won sile.