YBH 617

OLUWA mi, mo kepe O

1. OLUWA mi, mo kepe O
Ngo ku b’ O ko ran mi lowo;
Jo, fi igbala Re fun mi
Gbi mi bi mo ti ri.

Refrain
Gba mi bi mo ti ri (2)
Kristi ku fun mi l’ebe mi
Gba mi bi mo ti ri.

2. Emi kun fun ese pupo,
O ta ‘je Re sile fun mi
O le se mi bi mo ti ri.
Gba mi bi mo ti ri, etc.

Refrain
Gba mi bi mo ti ri (2)
Kristi ku fun mi l’ebe mi
Gba mi bi mo ti ri.

3. Ko si ‘le ti mo le pa mo,
Nko le duro ti ‘pinnu mi;
Sibe ‘tori Tire gba mi,
Gba mi bi mo ti ri.

Refrain
Gba mi bi mo ti ri (2)
Kristi ku fun mi l’ebe mi
Gba mi bi mo ti ri.

4. Wo mi! mo wole l’ese Re,
Se mi bi o ba ti to si,
Bere ‘se Re si pari re,
Gba mi bi mo ti ri.

Refrain
Gba mi bi mo ti ri (2)
Kristi ku fun mi l’ebe mi
Gba mi bi mo ti ri.

(Visited 2,457 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you