YBH 618

MO Fe mo nipa Jesu sii

1. MO Fe mo nipa Jesu sii,
F’or’ ofe Re h’ elomiran;
Ki nle ri ‘gbala kikun Re,
Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi.

Refrain
Ki nmo nipa Jesu sii,
Ki nmo nipa Jesu sii;
Ki nle ri ‘gbala kikun Re,
Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi

2. Mgo ko nipa Jesu sii,
Ki nda ‘fe Re mimo mo si i;
K’ em’ Olorun j’oruko mi,
Ki nmo nipa etc.

Refrain
Ki nmo nipa Jesu sii,
Ki nmo nipa Jesu sii;
Ki nle ri ‘gbala kikun Re,
Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi

3. Ki nmo Jesu si n’oro Re,
Ki nma b’Oluwa mi soro;
Ki nsi gbo ‘ro Re lokokan,
So ‘ro ‘tito Re di t’emi.

Refrain
Ki nmo nipa Jesu sii,
Ki nmo nipa Jesu sii;
Ki nle ri ‘gbala kikun Re,
Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi

4. Ki nmo Jesu l’ori ‘te Re,
Pel’ oro gbogbo Ogo Re;
Mo bi’joba Re ti npo si,
Bibo re Oba ‘lafia

Refrain
Ki nmo nipa Jesu sii,
Ki nmo nipa Jesu sii;
Ki nle ri ‘gbala kikun Re,
Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi

(Visited 722 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you