YBH 619

GBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aaye

1. GBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aaye
Nn’ orin at’adura, ale;
N’ alo at’ ife eba ina,
Ibagbe re si wa yi wa ka,
‘Gbagbo’ awon ‘ya wa, aaye ni,
Ao di o mu titi d’opin.

2. ‘Gbagbo awon ‘ya wa, aaye ni,
‘Bi ‘gbekele ‘t’ or’ofe ti nwa
Yiya si mimo re ba a le je,
‘Bere iran olola nla;
Igbagbo ‘ya wa, ife ni,
Ao di o mu titi d’opin.

3. ‘Gbagbo awon ‘ya wa nfona han ni,
Nnu ‘reti at’ aigbagbo odo,
B’oju at’ona wa tile sookun,
T’ao ko tile le r’itoju Re.
‘Gbagbo Iya wa, ti Kristi ni,
Ao di o mu titi d’opin.

4. ‘Gbagbo Iya wa, ti Kristi ni,
N’otito to ta ‘jewo way o,
O ntoju ‘le o si gba ijo la,
Iwa wa si nf’ emi re han;
‘Gbagbo ‘ya wa ti Kristi ni,
Ao di o mu titi d’opin.

(Visited 2,035 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you