1. NGO je ‘mole fun Jesu,
Ki ntan nigba gbogbo,
Ki ntan s’ ibi to fe mi,
Ki ntan l’ojojumo,
L’ oro ‘fe ati n’ ise,
Lo mi Oluwa mi;
Ki ntun ‘le on ‘le mi se,
Titi okun y’o fi lo
Refrain
Emi yio tan ‘mole nibiti mo le,
Ngo m’ okan funfun Jesu,
Titi d’ ojo na.
2. Egbe imole ntan,
Yika gbogbo aiye,
Ero awon omode npapo,
Ninu re Olorun,
Baba lo ailera wa,
Ko to eni gbogbo,
Si gbagbo bi t’ omode,
K’ aiye kun fun orin.
Refrain
Emi yio tan ‘mole nibiti mo le,
Ngo m’ okan funfun Jesu,
Titi d’ ojo na.
(Visited 213 times, 1 visits today)