1. A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re,
Fun Jesu ti o ku to si lo soke
Refrain
Halleluya, tire logo
Halleluya, Amin;
Halleluya, tire logo,
Tun mu soji.
2. A yin O ‘lorun, f’ emi ‘mole Re,
To f’ Olugbala han To mu ‘mole wa.
Refrain
Halleluya, tire logo
Halleluya, Amin;
Halleluya, tire logo,
Tun mu soji.
3. Ogo ati ‘yin f’ odagutan ta pa,
To ru gbogb’ ese wa to w’ eri wa nu.
Refrain
Halleluya, tire logo
Halleluya, Amin;
Halleluya, tire logo,
Tun mu soji.
4. Sa mu soji, f’ ife Re k’ okan wa;
K’ okan gbogbo gbina fun ina orun.
Refrain
Halleluya, tire logo
Halleluya, Amin;
Halleluya, tire logo,
Tun mu soji.
(Visited 638 times, 1 visits today)