ORIN t’o dun wa s’okan mi,
Orin ayo inu-didun,
Ngo korin alafia didun,
Ebun ife t’Olorun.
Refrain
A- la-fi-a;
Ebun ‘yanu lat’ orun!
Alafia t’o ga julo!
Ebun ife t’ Olorun!
2. Kristi lori agbelebu,
Ti san gbogbo igbese mi,
Ko si ohun miran t’ o le,
Ma alafia didun na wa.
Refrain
A- la-fi-a;
Ebun ‘yanu lat’ orun!
Alafia t’o ga julo!
Ebun ife t’ Olorun!
3. ‘Gba Jesu di Oluwa mi,
Alafia yi k’ okan mi,
Lodo Re mo r’ ibukun rere,
Alafia t’ orun wa.
Refrain
A- la-fi-a;
Ebun ‘yanu lat’ orun!
Alafia t’o ga julo!
Ebun ife t’ Olorun!
4. F’ alafia yi ni mo wa,
Mo si sunmo odo Jesu,
Lodo Re alafia wa,
Ebun ife t’ Olorun.
Refrain
A- la-fi-a;
Ebun ‘yanu lat’ orun!
Alafia t’o ga julo!
Ebun ife t’ Olorun!
(Visited 744 times, 2 visits today)