YBH 632

A RE mu o okan re poruru

1. A RE mu o okan re poruru?
So o fun Jesu, so o fun Jesu;
Ibanuje dipo ayo fun o?
So o fun Jesu nikan.

Refrain
So o fun Jesu; so o fun Jesu,
On l’ore ti yio mo,
Ko tun s’ ore
Ati ‘yekan bi Re,
So o fun Jesu nikan.

2. Asun-dakun omije l’ o nsun bi?
So o fun Jesu, so o fun,
O l’ ese t’o farasin f’ enia,
So o fun Jesu nikan.

Refrain
So o fun Jesu; so o fun Jesu,
On l’ore ti yio mo,
Ko tun s’ ore
Ati ‘yekan bi Re,
So o fun Jesu nikan.

3. ‘Banuje teri okan re ba bi?
So o fun Jesu, so o fun Jesu,
O ha nsaniyan ojo ola bi?
So o fun Jesu nikan.

Refrain
So o fun Jesu; so o fun Jesu,
On l’ore ti yio mo,
Ko tun s’ ore
Ati ‘yekan bi Re,
So o fun Jesu nikan.

4. Ironu iku mu o damu bi?
So ofun Jesu, so o funJesu,
Okan re nfe ijoba Jesu bi!
So o fun Jesu nikan.

Refrain
So o fun Jesu; so o fun Jesu,
On l’ore ti yio mo,
Ko tun s’ ore
Ati ‘yekan bi Re,
So o fun Jesu nikan.

(Visited 11,163 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you