1. B’O ti dun lati gba Jesu
Gbo gege bi oro Re;
K’ a simi lor’ ileri Re,
Sa gbogbo l’ Olyuwa wi.
Refrain
Jesu, Jesu emi gbagbo,
Mo gbekele ngbagbogbo;
Jesu, Jesu, Alabukun,
Ki nle gbekele O si!
2. B’ o ti dun lati gba Jesu,
K’ a gb’ eje ‘wenumo Re;
Igbagbo ni ki a fib o
Sin ‘eje wenumo na.
Refrain
Jesu, Jesu emi gbagbo,
Mo gbekele ngbagbogbo;
Jesu, Jesu, Alabukun,
Ki nle gbekele O si!
3. B’ o ti dun lati Jesu,
Ki nk’ ara ese sile;
Ki ngb’ ayo, iye, isimi
Lati odo Jesu mi.
Refrain
Jesu, Jesu emi gbagbo,
Mo gbekele ngbagbogbo;
Jesu, Jesu, Alabukun,
Ki nle gbekele O si!
4. Mo yo mo gbeke mi le O,
Jesu mi, Alabukun;
Mo mo pe O wa pelu,
Ntoju mi titi d’ opin.
Refrain
Jesu, Jesu emi gbagbo,
Mo gbekele ngbagbogbo;
Jesu, Jesu, Alabukun,
Ki nle gbekele O si!