1. KO s’ ore bi Jesu onirele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Refrain
Jesu mo gbogbo idamu wa,
Y’o toju wa d’ opin ojo;
Ko s’ ore bi Jesu onirele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
2. ko s’ ore bi Re t’ o ga ni Mimo,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Ko s’ ore t’ o tutu, t’ o ni ‘rele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Refrain
Jesu mo gbogbo idamu wa,
Y’o toju wa d’ opin ojo;
Ko s’ ore bi Jesu onirele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
3. Ko s’ akoko ti On ko sunmo wa,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Ko s’ oru ti ‘fe Re ko tu won n’nu
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Refrain
Jesu mo gbogbo idamu wa,
Y’o toju wa d’ opin ojo;
Ko s’ ore bi Jesu onirele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
4. Enikan ha ti r’ ore yi nko ni
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Tab elese ri ko ni gba on la?
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Refrain
Jesu mo gbogbo idamu wa,
Y’o toju wa d’ opin ojo;
Ko s’ ore bi Jesu onirele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
5. Ebun kan ha wa bi Jesu fun wa?
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Y’o ha ko fun wa k’ a n’ ile l’ orun?
Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Refrain
Jesu mo gbogbo idamu wa,
Y’o toju wa d’ opin ojo;
Ko s’ ore bi Jesu onirele,
Ko s’ okan! Ko s’ okan!