YBH 660

OHUN ipe kan ti, oke petele wa

1. OHUN ipe kan ti, oke petele wa,
S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist,
Oke gba orin na, gege b’o ti ndun lo,
T’ olotito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

Refrain
Lo si isegun, lo si isegun,
Ni ase Balogun wa,
Ao lo li ase Re laipe ao gba ‘le na
Pel’ otito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

2. Enyin akin e gbo, iro to mi aiye,
S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist,
E dide e sise, kede otito na,
T’ olotito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

Refrain
Lo si isegun, lo si isegun,
Ni ase Balogun wa,
Ao lo li ase Re laipe ao gba ‘le na
Pel’ otito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

3. Wa dapo m’ egbe wa, ao Omiran na,
S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist,
Ao fun ipe ogun, s’ ori ogun Esu,
T’ olotito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

Refrain
Lo si isegun, lo si isegun,
Ni ase Balogun wa,
Ao lo li ase Re laipe ao gba ‘le na
Pel’ otito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

4. A fi agbara wa le Oluwa lowo,
S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist,
Ao kede ‘gbala Re yi gbogbo aiye ka,
T’ olotito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

Refrain
Lo si isegun, lo si isegun,
Ni ase Balogun wa,
Ao lo li ase Re laipe ao gba ‘le na
Pel’ otito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.

(Visited 402 times, 4 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you