YBH 565

TANI yio gbe Jabob’ dide

1. TANI yio gbe Jabob’ dide?”
Ore Jakob’ kop o;
Eyi t’ o je ‘yanu nip e,
Imo won ko s’ okan.

3″Tani yio gbe Jakob’ dide?”
Ota Jakob’ n’ ipa;
Mo r’ ayo ‘segun l’ oju won,
Nwon ni o pari fun.

3. “Tani yio gbe Jakob’ dide?”
A ha r’ eni le wi?
Eka t’ o ro nibule yi
O ha tun le ye mo?

4. Oluwa mi, ise Re ni!
Ko s’ emi t’ o le se;
Se b’ iri s’ ori Jakobu,
On yio sit un ye.

(Visited 1,358 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you