YBH 566

OLORUN fe araiye

1. OLORUN fe araiye,
O fe tobe ge,
T’ O ran Omo Re w’ aiye
T’ O ku fun elses;
Olorun ti mo tele
Pe, emi o se si
Ofin ati ife Re;
Iwo ha fe Mi bi?

2. Loto, Olorun fe mi,
Ani-ani ko si,
Awon t’o yipada si
Igbala ni won ri;
Wo! Jesu Kristi jiya,
Igi l’a kan a mo,
Wo! eje Re ti o nsan,
Wo! ro ma d’ ese mo.

3. Jesu s’ agbelebu Re,
Ngo kan ese mi mo;
Labe agbelebu Re,
Ngo we ese mi nu;
Nigbat’ emi o ri O,
Ni orun rere Re,
Nki yio dekun yin O,
F’ ogo at’ ola Re.

(Visited 428 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you